Pages

Friday, 9 September 2016

%100 VERIFIED 2016 WAEC GCE YORUBA LANGUAGE OBJ AND ESSAY ANSWERS

YORUBA ANSWERS

2a ) Iro akuyun : Awon konsonanti ti agbe jade nigba ti alafo tan -an - na gbon riri Iro aikunyun: Eyi ni awon konsonanti ti agbe jade nigbati alafo tan - an -na wa ni ipo imi ,eemi ri aaye gba inu alafo yii koja woorowo

2b ) Iro akunyun -d ,gb ,m Iro aikunyun-p ,k , f =========================

4 a) Mofiimu ni ege isapejuwe to kere julo ti osi ni itumo kikun tabi lilo ninu ihun oro 4 b) i – Idaro -i + idaro ii- Omuti- O + muti iii-ilegbee -ile + gbee iv -Olopo -O+ lopo v -eranko – eran + oko vi -Ountaja – oun+ taja vii- Ailowolowo -Ai+ lowo + lowo viii -Omodekunrin -Omode + kunrin ix-Akope -a + kope x- Akowe-a + kowe xi-pejapeja -peja + peja xii – omokomo- omo+ ki + omo

5a) O' sese lo ni O' eni keta eyo ni ipo oluwa

5b) Se e. ti se tan E. leni keji opo nipo oluwa

5d) A pade yin lona lanaa A eni kinni opo nipo oluwa

5e) Titi fa iwe mi ya mi Eni kini eyo ni ipo abo

5e.) Jide bu won won eni keta opo nipo abo ===========

12a) Akuruyejo, Agoro, Ajisefini, idi ileke, ogini. ajanaku, folami, idi aran, orebe,, ajisafe, arowojobe

12b) Abeke, apeke,ariyike, ajoke,alake,adio, alamu, alao

12e) Babatunde, durojaye, malomo,kokumo ,enibolobo, igbekoya ,kilankorotimi ,kukoyi ============

No comments:

Post a Comment

Disclaimer: Opinions expressed in comments are those of the comment writers alone and does not reflect or represent the views of NAIJASHOT.COM......... thanks