Yoruba
Verified Yoruba Obj
1-10 daebddbebe
11-20 eabddbbbeb
21-30 babbbdabdc
31-40 acdeeecbcc
41-50 bbbbccccsb
51-60 bddeacddce
YORUBA ANSWERS

No2a)
copied from Gurusgist. com
1, รณ- oro aropo oruko
2, elewe- Eyan akanmoruko
3, ewura- Eyan ajoruko
4, Meji- Ryan asonka
copied from www.gurusgist.com
2ai) O- pro aropo orukp eniketa,ni IPO eyo
2.) Elewe- Ryan akanmoruko
3) Ewura- Eyan ajoruko
4) Meji- Eyan asonka
5) Ko- asaaju pro use
6) Pupo- Aponle
7) Awon- Aropo afarajorukp
8) ni- atokun
9) oun- asopo
10) pelepele- aponle
copied from www.gurusgist.com
===============================
(7)
-Ibalaga
-Ifojusode
-Itoro
-Ayewo sise
-Owo ori sisan
-Idana
-Igbeyawo
-Ibalag:Okunrin to bati balaga ni onfe iyawo nitori okunrin bee gbodo ni owo lowo lati le toju iyawo ati omo
-Ifojusode:Okunrin yio wa eni ti owu nipa fifi oju sode
-Alarina:Alarina yio se asotun sosi ni odo oko ati iyawo ki oro won lewo
-Itoro omo:Ati igba ti oro okunrin ati obinrin bati wo awon obi okunrin yio yoju si awon obi obinrin lati toro omo won
-Ayewo sise:Awon obi okunrin ati obinrin ti idile oko yoo sisan owo ayewo leyin eyi ni ojo mimo obi iyawo
-Owo ori sisan:Awon ebi oko yio san owo inawo ikobi iyawo ni:Igba orogbo,igba obi,opolopo isu ati agbado, won yio si ojo fun igbeyawo
-Igbeyawo:Eyi ni sisin iyawo losile oko ,sisun ekun iyawo.Ale ni elegbe iyawo n mun losile .Bibori fun iyawo fifi ese fo igba ko to wole ati beebee lo
===================================
(9)
Mo gbo ariwo,enikan n yo kelekele ni eyin ferese mi,mo ri ojiji ni imole oru,leyin eyi ni mo ri owo ti o koja lo sibi ferese naa.Eru baami,mo pa oju mide ti mo si piroro bigbati oun koun kosele.Ko rorun fun ole na lati gba ibi ferese wole nitori galagala naa je tuntun ti osi nipari.Nigbati mode ede ole na ti gbiyanju lati si ilekun,Mogbo da duro,Amo bawo?tio ba ni obe tabi ada nko?Emi kosi ni ounkoun.Lojiji ese mi kan nkankan oje odo iya mi tuntun.Eyi ni oun ija mi.Mo si piororo sibi ilekun.Ilekun naa si diedie mo si ri oju okunrin na ninu imole oru.Mo gbe omo odo na mo si jan mon lori.Osi subu lule yakata.
=====================================
(10)
Mo dupe lopolopo
Mi kole se awawi
Ife tio wa lasan wa
ti wo inu opolo ni
Ife mi tooto
ti awon miran koleri
Ti awa gbiyanju latiri
o tako lakaya osi foju
Mi ko so rara pe
Ife wa ko tawa tegbo
sugbo n semi
Oni iwo ati irungbon
Idi re ni wipe
Mo feran re pelu gbogbo okan mi
Je kia jo sise po lai kaa re okan
Lati gbara le enikeji fun aseyori
Ka pa awadw ti
Mo feran ololufe mi
Mo mo ipe wa ran mi lowo
di igbeyin aye mi
More loading.
No comments:
Post a Comment